Agbara Imo Ala ati Irawo

Agbara Imo Ala ati Irawo Help you for any consultation and check up: medical and spiritual
Prayers and delivery services,..

01/04/2024

*Wishing you the most beautiful things in this new month of _April_, as you aspire for the hope of Allah. May the blessing of the Almighty Allah be blended with your success in life. Wishing you a fantastic new month*

_Happy New Month ❄️_
*ARRAZQIY INTERNATIONAL cares* ❤️❤️❤️❤️*

24/03/2024

*ÀLÀYÉ ATI ÀKÍYÈSÍ LÓRÍ ỌKỌ TABI ÀYÀ ÒRUN (SPIRITUAL LOVERS)*

👇👇👇👇👇

Ọpọlọpọ eda ènìyàn nii ko m'ope ipinle ogun ayé ohun nii ọkọ tàbí aya orun

Njẹ iwọ mọ pé irú àwọn nkan wonyi kii ùn jeki àṣeyọrí waye larin iru enibe ati ololufe rẹ

Njẹ iwọ mọ pé àyà tabi oko orun kii ùn fe tete ribi sini bíi akoba mura daada
Gege bíi àpẹẹrẹ

👇👇👇👇👇👇
*OBINRIN*

Obinrin tii oko orun ba unda laamu gbogbo igba nii yio ma la Ala ibalopo loju orun iruwon kii untete bimo.
Beesini bii wonba nii oko oseese kii ise okowon Mase tesiwaju nitoripe OKO orun amabinu sii oko Aye
Kii ntun se iyen nikan gbogbo Owo tii iyawo ba untu Joo latifise ikan rere asan Lori Asan nii ayafii kii ogbiyanju lati bo ninu wahala yii

*IPADE OKO ORUN*

Bii eniti obani oko orun baa unsaba ma unrin lorita meta daada oko ee amapade ee nibe besini Ifaseyin nii gbogbo ikan bayii ma unfa sinu aye oko tii obagbe iru obinrin bayii sile

*ENITI oni oko Orun ma unsaba feran lati maa sun NINU okunkun iru ikan bayii ma unb ayo opolopo alabagbe won jeni.

*Oko Orun ma npade iyawo ee nii ojo THURSDAY NINU Oja (market) kosi irufẹ ilu tabi orile-ede tii ohun kii owa Ema padà saa nii tii kii ùn base nii oru ẹni lati pade nii
Yala nipasẹ ala tabi lilọ sí ọjà

Bẹ sini awon ona kan wa lati mọ obinrin ti ọkọ orun ùn da'mu
👇👇👇👇👇👇

*ONAA LATI MO OBÌNRIN TI ỌKỌ ORUN UN DÁ LÁÀMÚ*

*OKUNRIN tii obafewon ma nsaba fii oju ATI ara ko owu alantakun daada nitoripe ijakule nii gbogbo igba nii oma nsaba waye fun iruwon

*Iru enibayii ama Saba maa lala ibalopo loju orun tii asi maa gbadun ee ju tii oju ayelo.

*Iruwon kii unsaba tete rii omo bii loju aye sugbon Inu egbe wonti bimo Repete fun oko orun idi niyi tii won fii maunso fun obiinrin imiran pe oti bimo daada tii asima jiyan pe owun kobimo rii.

*Die ninu won maa unrii promise and fail lodo okunrin nitoripe OKO won lorun Ma unda ise okunrin Toba fewon ru oseese kii iru obiinrin bayii nii ijakule ife.

* Wonkii unsaba maa unfe kii isoro won kuro lara won.nitoripe OKO orun kii unfe fii iyawo ee sile besini opolopo igba nii Oro won kii un ye awon naa
ancestorolalekan@gmail.com

*AYA ORUN*

Wahala unla nifun okunrin Tii obani Aya orun Nitoripe kowopo ninu awon okunrin Tii Oni aya orun sugbon eyii tii obani kii unsaba ma unse Aseyori pelu Awon Obinrin tii obaunfe
Ija Loni ijalola nii kii unse ejo owun naa bii kii unsepe Awon isoro Aye ee nii.

*DIE NINU ỌNA TI WON FI UN MỌ ẸNITÍ ÀYÀ ÒRUN DA LÁÀMÚ*

*Iru Awon enibayii konisi ilosiwaju kankan funwon. Yala nibi ise tabi Inu Ile

*Iruwon kii unsaba ma unkonu sii obinrin nitoripe Eru ma unbawon.

*Iruwon ma unsaba ma un ma******te dipo kii won nii Ibalopo (s*x ) pelu obinrin nitoripe ikanyii ma undun mowon gan

*Iruwon kii unsaba gbe ikan rere see laye konisi Owo 💴 besini konibimo awadabi ejo Ori Apata

*DIẸ NINU MAJẸMU TI WON MA UN DA*

* ELOMIRAN Ma unfi ọjọ́ ikùn lè ( labouring day) búra wipe ojo yii nii oun yio pada

*Elo miran ma unfii ojo IGBEYAWO( wedding day) bura wipe ojo yii nii oun yio pada

* Bakan naa ojo ikomo jáde ( naming ceremony)àti bebelo.

Ogun kii un tete sise Lara eniti Aisan yii ba ndalamu nitoripe awon ololufe won kii unfeki won fii awon sile Adura ATI igbiyanju topeye nii afii nbo lowo OKO ATI AYA ORUN.

Ọlọhun koni dojú adua tiwa

*AWỌN AṢỌ TI OBA KÁDÀRÁ IRAWỌ IKOKAN MUAimokan ti sọ ẹlòmíràn sinu ìgbèkùn ayérayé bẹ sini iyemeji tii sọ ẹlòmíràn dii ẹ...
06/03/2024

*AWỌN AṢỌ TI OBA KÁDÀRÁ IRAWỌ IKOKAN MU

Aimokan ti sọ ẹlòmíràn sinu ìgbèkùn ayérayé bẹ sini iyemeji tii sọ ẹlòmíràn dii ẹni ẹyin Ose pàtàkì kii amo irawọ tii a ùn lo bẹ sini anilati mo awọn aṣọ tii o ba irawo wa mu.
Nítorí pé bíi eda koba kii ùn wọ aṣọ tii ọba ipin irawo ee mu odidandan kii Ifaseyin ma ṣẹlẹ síi.

*IRAWỌ OMI*

Meta níí ipin irawo yìí

AGBÁRA OMI ♋ CANCER

OMI TIKIRU PIECES♊

OMI TÚTÚ SCORPIO♏

Odara kii gbogbo ipin irawo yìí má wọ àwọn Asọ báyìí.

FÚNFÚN

OMI ARO

OFF WHITE

GREEN

BROWN

*IRAWỌ INÁ*

Meta níí gbogbo irawo yìí náà Pin síi

INÁ ATUPA SAGITTARIUS♐

INÁ TONGBONA RIRI ♌ LEO

INÁ TONKANYANRAN ♈ ARIES

Irawọ yii féràn láti máa wọ àwọn aṣọ wọnyi

PUPA

( ṣugbọn ẹnití Obaje emere omi ninu wọn níí gbogbo igba ti won ba wo a*o pupa ara ma ùn níwòn)

GOLDEN COLOR

GREEN

YELLOW

WHITE

*IRAWỌ ERUPẸ*

Ona meta níí gbogbo ipin irawo yìí na pinsin bẹ sini koṣe maa níí irawo yìí jẹ láwùjọ gbogbo irawo

ERUPE FÚNFÚN ♍ VIRGO

ERUPẸ AMO TAURUS♉

ERUPE ERUKU CARPRICON♑
Awọn aṣọ tii odara kii irawọ yìí má wọ níí yìí.

PINK

PURPLE

WHITE

CREAM COLOR

LEMON GREEN

Eleyii tii iṣẹ rẹ bá jẹ Mọ pé kii o wọ aṣọ dúdú as uniform iru wọn gbọdọ wọ aṣọ funfun gẹgẹ bíi awọ tẹlẹ.

*IRAWỌ AFẸFẸ*

Ipò irawo yìí níí agbara ju gbogbo irawọ tii oku lọ iwuwasi wọn yàtọ gedengbe bẹ sini won kìí ùn se fii ara wẹ láwùjọ irawọ
Meta níí ìpín wọn bẹ sini won níí agbara ju arawọn lọ gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ

AFẸFẸ ONIBINU AQUARIS♒

AFẸFẸ ALAWADA ♊ GEMINI

AFẸFẸ MARINMIFIN ♎ LIBRA

Iyalẹnu níí pe kosi irufẹ aṣọ tii won ko le wọ.
Njẹ iwọ tun wa mọ pe won tun níí awọn ewọ kan tii won kogbodo ṣe lori aṣọ wiwọ

*ÀKÍYÈSÍ*

Irawo yìí kogbodo wọ aṣọ dúdú sun

Irawọ yìí kogbodo wo aṣọ alarambara sun

Olohun koni jeki Awaye asan. Amiin.

*AWỌN AṢỌ TI OBA KÁDÀRÁ IRAWỌ IKOKAN MU

Aimokan ti sọ ẹlòmíràn sinu ìgbèkùn ayérayé bẹ sini iyemeji tii sọ ẹlòmíràn dii ẹni ẹyin Ose pàtàkì kii amo irawọ tii a ùn lo bẹ sini anilati mo awọn aṣọ tii o ba irawo wa mu.
Nítorí pé bíi eda koba kii ùn wọ aṣọ tii ọba ipin irawo ee mu odidandan kii Ifaseyin ma ṣẹlẹ síi.

*IRAWỌ OMI*

Meta níí ipin irawo yìí

AGBÁRA OMI ♋ CANCER

OMI TIKIRU PIECES♊

OMI TÚTÚ SCORPIO♏

Odara kii gbogbo ipin irawo yìí má wọ àwọn Asọ báyìí.

FÚNFÚN

OMI ARO

OFF WHITE

GREEN

BROWN

*IRAWỌ INÁ*

Meta níí gbogbo irawo yìí náà Pin síi

INÁ ATUPA SAGITTARIUS♐

INÁ TONGBONA RIRI ♌ LEO

INÁ TONKANYANRAN ♈ ARIES

Irawọ yii féràn láti máa wọ àwọn aṣọ wọnyi

PUPA

( ṣugbọn ẹnití Obaje emere omi ninu wọn níí gbogbo igba ti won ba wo a*o pupa ara ma ùn níwòn)

GOLDEN COLOR

GREEN

YELLOW

WHITE

*IRAWỌ ERUPẸ*

Ona meta níí gbogbo ipin irawo yìí na pinsin bẹ sini koṣe maa níí irawo yìí jẹ láwùjọ gbogbo irawo

ERUPE FÚNFÚN ♍ VIRGO

ERUPẸ AMO TAURUS♉

ERUPE ERUKU CARPRICON♑
Awọn aṣọ tii odara kii irawọ yìí má wọ níí yìí.

PINK

PURPLE

WHITE

CREAM COLOR

LEMON GREEN

Eleyii tii iṣẹ rẹ bá jẹ Mọ pé kii o wọ aṣọ dúdú as uniform iru wọn gbọdọ wọ aṣọ funfun gẹgẹ bíi awọ tẹlẹ.

*IRAWỌ AFẸFẸ*

Ipò irawo yìí níí agbara ju gbogbo irawọ tii oku lọ iwuwasi wọn yàtọ gedengbe bẹ sini won kìí ùn se fii ara wẹ láwùjọ irawọ
Meta níí ìpín wọn bẹ sini won níí agbara ju arawọn lọ gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ

AFẸFẸ ONIBINU AQUARIS♒

AFẸFẸ ALAWADA ♊ GEMINI

AFẸFẸ MARINMIFIN ♎ LIBRA

Iyalẹnu níí pe kosi irufẹ aṣọ tii won ko le wọ.
Njẹ iwọ tun wa mọ pe won tun níí awọn ewọ kan tii won kogbodo ṣe lori aṣọ wiwọ

*ÀKÍYÈSÍ*

Irawo yìí kogbodo wọ aṣọ dúdú sun

Irawọ yìí kogbodo wo aṣọ alarambara sun

Olohun koni jeki Awaye asan. Amiin.

Note! Adamo erupe: ki won Sora Lati ma wo a*o purple pupo tabi sun lale Tori Koma ma fa wahala ati idamu fun won,...ki won ma se, ma si Ori won kale sun lale,..

Aries, ki won mawo a*o pupa si isale a*o won ni ooo, Tori ki won ba tete Mari Anu gba....

Pisces: ki Sora Lati mawo a*o funfun ati brown papo Tori iseda won tako, odara pupo fun won, ki won ma wo a*o funfun ati kiwon ma da Bora sun lale....ki won si ma tan imole fun sun lale, odara fun awon iseda Omi toku Na,ki Sora Lati ma ni ibalopo( s*xual in*******se) Lati eyin( doggy style) e.t.c ati iseda erupe, Tori! Yoma di agbara adua Ku Lara ati iyanju, medically and spiritually; yoma agbara isan( vein) won Ku ninu araron,ati agbega won ninu aye....

Fun afani, agbega ati ayipa rere ninu aye re, isegun Amubo ati promise and failed, Sora fun afowafa, kosi ma nipa iseda, akosejaye re, irawo dada, lore-korere....

My WhatsApp number or call
08105428760

29/02/2024

Awon egbe irawo omi, won pin si meta: CANCER(ALAKAN), SCORPION(AKEKE), PISCES ( EJA)...

Awon ti won bamu adamo or irawo Omi wa si aye, ma saba je eniyan jeeje, won kin tete binu, sugbon won ma saba yan di ninu iwa won, won ma saba ma nro ara won pin nigba ti adanwo ba de siwon, awon egbe won si saba ma dawon pupo lori iriajo aye won lata ri, ti won nba rin irin tiko ba, eleda won lara mu,adua won si tete nma gba, ti won nba se adua sinu omi tabi hantu, tira, won o tete kona lo pelu Sara, toba won lara mu...
Awon elegbe won si feran anu pupo, sugbon won ki rira njan dudu....

AWON OMO OMI

Awon ISEDA OMI ma ri awon egbe won dada loju orun tabi loju ran pelu wipe ti won RI ona ti o ye karin pelu ILANA to to....
Awon omo omi kan wa to je PE ADUA fun eleda won ATI Sara to ye NI awon egbe won nfe, nijo ti ba ti bere, ijo na ni ayipada tide saye won...

Awon omo omi kan wa toje pe, kiwon jina si nkan ewo won NI, awon egbe won yo fi fara han won KIAKIA, Koda tiwon yosi mase ipade ninu aye... Pelu awon majemu ti eledua fi seda won...

Awon omo omi kan wa ti afun ni ase ti nbe Lara won, toje PE, TI won ba mojuto ASE yi( NI ori ni, abiya NI, oju ara e.t.c) TI won bape ojo ori kan ninu aye, awon egbe won yo fi ara han won dada, TI nsi sele ninu pelu research todaju, TI AO si ba be...

By AR-RAZAQIY INTERNATIONAL
WhatsApp number or call
08105428760
By AR-RAZAQIY....

AMOJUTO FUN GBOGBO IRAWO FUN ONA ATILA ATI RIRESE WON KIAKIA PELU IMO ASTRONOMY ( ORUKO) ATI ASTROLOGY ( OSU).....Pelu i...
27/02/2024

AMOJUTO FUN GBOGBO IRAWO FUN ONA ATILA ATI RIRESE WON KIAKIA PELU IMO ASTRONOMY ( ORUKO) ATI ASTROLOGY ( OSU).....

Pelu imo astronomy ( oruko) ATI astrology ( osu), lafin ma ona asiki,ATI ije imu, ATI ona atila NI olohun ko ma iseda kokan lati tete be GBE PE...

Awon IRAWO (ADAMO) afefe; won pin SI ona meta: BURUJI Gemini ( afefe ALAWADA), BURUJI Libra ( afefe MARIMIFIN), BURUJI Aquarius ( afefe ONIBINU), awon irawo irawo afefe yi, won ma Saba feran iriajo, won SI Saba ma feran lati soro tabi koyan maran pelu eni tiwon ba feran, ibikibi TI won bawa nma dun, won ma feran awada ATI ikoyan mara, won ma feran lati se nkan toma yato SI telo Miran, won Saba NI ifarada nigbati wahala kan bade, won ma Saba fi ikanju see nkan, to je pe, TI won ko bati see ikan tan, won tun ma see imi, ikan yen sima pawon Lara PUPO lati tete se aseyori, won ki ma owo kan lai na, suru won ki Saba pe pupo ra, AFI TI won koba fe soro, Tori won ki Saba RI Oro GBE SI emi won, won ki Saba di yan sinu, won ma Saba to pinpin nkan pupo, won Saba gbara le yan gan, won ma tete binu si nkan TI pa pawon Lara,...
Ogun dudu ki Saba sise Lara won, Tori iseda won Kori ra re PUPO, sugbon pelu adua ATI oruko olohun to ba ISEDA won mu ati Sara to ba ISEDA irawo yi kokan mu, nijo tiwon bati she, NI ayipada, ATI oun rere, yo TI ma sele sinu aye won Kia Kia,..... WALLAHU A'LAM...
GBOGBO ENI TOBA SHARE RE, FUN AFANI ELO MI, AO NI WA AYE ASAN OOO
OLOHUN YO FIWA MANA...

BY AR-RAZAQIY INTERNATIONAL
WhatsApp number or call
08105428760

26/02/2024

*ÀLÁ ÀTI ÌTUMỌ PẸLU ỌNA ABAYỌ*

Ona tii awa eda ma ùn gba la ala pọ já ùn ti rere bẹ síni kii ùn se gbogbo awa eda eniyan nii ama ùn rántí àwọn ala ti aba la

Aya fii kii ato oni mimo lo kii alari solution síi ìtumọ awọn ala wa
👇👇👇👇👇

Bíi obalala pe oun lu ọmọ bíbí inú rẹ lójú àlá nii gbogbo igba
Itumo:- ọmọ náà yóò ya iyakuya

Bíi obalala pe oun ba ara-re nii ilé ìwé akoko bere tabi Gírámà tìí oti jade nii ọpọlọpọ ọdun sẹyin.
Ìtumọ:- Àmì Ifasehin nii tẹra mọ adua

Bíi ọkọ àti ìyàwó ba ùn saba lala pe awon ùn gba ilẹ 🧹 nii gbogbo igba
Ìtumọ:- ija yóò ma ṣẹlẹ laarin wọn.

Bíi obalala pe oun jẹ ọgẹdẹ 🍌 loju ala
Ìtumọ:- ikan irọrun yóò ṣẹlẹ sí ee

Bíi obalala pe oun se menstruation loju ala nii gbogbo igba
Ìtumọ:- wa ṣe aṣédanu lori ikan tii oun dawole

Bíi obalala pe oun daana ounjẹ fún ọpọlọpọ awọn awọn eniyan. Loju ala
Ìtumọ:- wa fa ifasehin fún àwọn tii wọn sun mọ rẹ

Bíi obalala pe. Won fún ee nii òbí jẹ lójú ala
Ìtumọ:- wa je májèlé oju òrun

Bíi obalala pe oun jẹun loju ala leyin tii ojisaye tan gbogbo inu rẹ wa wú bamu bamu
Ìtumọ:- ikorira ati ijakule nii

Bíi obalala pe oun ríi ẹyẹlé loju ala nii gbogbo igba
Ìtumọ:- wa ko oore jọ nii gbogbo ona

Bíi obalala pe oun seré létí òkun nii gbogbo igba loju ala
Ìtumọ:- elegbe ọmọ nii ee tete se awari arare

Bíi obalala pe won fún ee nii oromo Adiye lójú àlá
Ìtumọ:- wa gba àlejò tii wa sìn

Bíi obalala pe o rẹwa ju bíi ọsẹ walo loju ayé
Ìtumọ:- wa ṣe àìsàn òjìji tii yóò mú ikú dání.

Bíi obalala pe oun là Oyin 🍯 loju ala
Ìtumọ:- ikan idunnu nbọ fún

Mogbadura fún gbogbo wa pé iku ojiji dii ewọ fún èmí ati iwọ,ati awon ebi wa lapapo...

Fún àmoran lórí ala call or Whatsapp 08105428760

IBASEPO ALA ATI IRAWO
Gbogbo irawo kookan nii Oni ibasepo pelu Ala Lila tii gbogbo Ala sije oun akoni soona gege bii Apere;

Tii obalala pe Ori Eyele funfun loju Ala
Itumo:- ire Ayo re yio te lowo.

Bii obalala pe oun kaa irawo oju orun
Itumo:- olohun yio se oore Arimalelo fun ee.

Bii Alaboyun Balala or oun fii Eja sere
Itumo:- ojo ikunle ee koni nira.

Bii obalala pe oun rii Arare larin Oja nii gbogbo igba
Itumo:- warin irin Ajolosi ilu giga

*IPIN FUN IRAWO KOOKAN* .

1. Irawo ina: eniyan toba nlo irawo yi amaaje eniyan toma nni ambition NLA NLA.kio maselo OSE dudu tiapo mo ebu ki ole maari erongba re. Eni toba gbiyanju Dada,yio han ninu igba,yio si pe laye.

2. Irawo omi: Eni toba nlo irawo yi yiomaaje eniti oferan oge sise, yioma ma wu lati je olowo gaaan,toba gbiyanju daada si aye araare,tiosin nse saara egbe re daada,ara koni ni.yiosimaari OWO nan.

3. Irawo erupe: Eni toba nlo irawo yi yioje akinkanju eniyan,yiosi tunje odaju nigbamiran, aaye ti irawo iyepe bawa,gbogbo irawo tinba nbe laaye nan asimaa beru re. Toba gbiyanju gan,yio mafi akin je olori kaakiri ni.

4. Irawo Afefe: eniti oba nlo irawo yi,yio han,yio si maa ko ero Jo,yio si je alawada tikogba oro iwosi. Eniyan toba nlo irawo yi. onilaakaye ni opolopo won ma unje. Bioba gbiyanju gaan,yiori aye lo daada

26/02/2024
*Okunfa gbese ati promise and failed+ disappointment pelu ISEDA* Tito bi olohun, oba eto, oba oluda EDA Pata, tio mo top...
26/02/2024

*Okunfa gbese ati promise and failed+ disappointment pelu ISEDA*

Tito bi olohun, oba eto, oba oluda EDA Pata, tio mo topamo, tio ma nkan tohan(the greatest), ko jeki gbogbo wa, Kari TIWASHE laye, ki a ri Anu nla gba Lorun...
Olohun Seda Omo araye pelu Eto (systems) irawo mejila , gbogbo EDA eniyan Toda saye Pata ounka wa JE 1020,... 400 si orile tawa Yi, 620 sinu Omi, lofa Tofi je PE orisi nkan lama ri ninu Omi...
Awon IRAWO mejila tolohun fi sakoso Omo eniyan Tofi dori Earth tawa Yi, awon IRAWO Yi lao mojuto pelu iseda wa ati egbe tawa pelu IMO Astrology and Astronomy( Oruko), lofa Ogun gbese, wahala,idamu, airomobi, promise and failed, amubo ati gbigbadua....
Irawo Mercury( ANU ATI AJE): Oun lo dari buruji meji( jazahu ati sunbula): egbe ALAKISA tabi ALARAGBO( JAOZAHU)
Egbe emere ORUN tabi Omo OMI AJE(sunbula) awon emi AIRIWON, won pase Ni sanmo kefa ati eketa(JAOZAHU)
Awon iseda yi won ma Ni OWO ATI Oro(wealth) Kojo laye pupo lati kekere bi 20years....adua won si tete maun GBa, tiwon base adua fun tabi fun rawon yomagba, sugbon ti won ba ti nshe nkan afowofa tabi won se oroju Lori nkan ti iseda won fe(nibi ADUA toye,tabi Sara nkan inu eran nipari OSU etc..), ki okunrin irawo kiwon majeki orun won ma kunju tabi obirin kiwon ma Bo ori won, ki won Jina si, nkan didun e.t.c.... koni si Aisan Ara tabi GBESE Loro won, tabi promise and failed, amubo, ninu Oro won pelu iyonda olohun, sugbon aun se afowofa, ao SE nkan toye fun ISEDA, awa pariwo gbese, ao Paro tan arawa wipe aunse adua, mojuto arare wari wipe WALAHI Adua ngba bi Tati Jo(kolohun maje Kari apada si aburu+Amin), je ki awon ojogbon kiwon se TEST OR check-up fun o pelu iye Toba wuwon latigba fun ise won ,fun eni toma nkan ti nshe, tofe otito Oro, Toberu atunbotan,toma wipe kororun lati ko imo Yi Jo pelu research lojojumo, ALMIGHTY KNOWS BEST....
Fun isegun GBESE tabi promise and failed.... Ekotutu1,orogbo(6+3=9), sugar, iyo Didi 9, DUPE, SHARE re fun afani Elo mi, yo je fun wa🙏 SARA fun alubara,3days lafi se....

ARRAZAQIY international
My WhatsApp number or call me
08105428760

Address

Ilorin
Lagos

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Agbara Imo Ala ati Irawo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Agbara Imo Ala ati Irawo:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram