Itoju Omode Agba Aboyun Itumo Ala Ati Ona Abayo Fun Won

Itoju Omode Agba Aboyun Itumo Ala Ati Ona Abayo Fun Won In God we trust

13/04/2024

TURARI ISEGUN TI A FI NLE AWON EYAN BURUKU KURO NI AYIKA WA
ISE NA RE
Imi ojo (surphur)
epo obo die
Ikun ojia
lo gbogbo e po ka psalm 24 and 35 si ma fi fin turari lale ni Tuesday and Friday a ba wa lara mu
Fun alaye lori ise yi e pe number yi 08145707383

13/04/2024

OSE RIRI TI AJE SE
gbogbo a da wo le wa la yori si rere
Ewe ogbo oojo(fresh)
Kafura pelebe roll kan
gun mo ose funfun 6 lux or joy ko kuna dada
a ma fi we pelu adura laro kutukutu. a ba wa lara mu
Fun alaye lori ise yi e pe number yi 08145707383

13/04/2024

Mo ki wa ku ojumo ninu yara alayo yi, anu olorun ko ni fi wa sile amin
mo fe fun wa ni asiri ti a fi ma ri owo ti a ba fe se inawo, asiri wa o ni tu lagbara olorun alaye
OSE ASIRI BIBO FUN INAWO
ise na re
E ma lo wa alubosa pupa, a ma lo kuna dada a ma po mo ose toba wuwa a ma ko s**e funfun a ma fi we larolaro pelu adura asiri wa ko bo. a ba wa lara mu fun alaye lori ise yi e pe number yi 08145707383

08/04/2024

FUN ENI TO NWA ISE GIDI
mo ki wa ku ojumo ninu yara alayo yi adura wa a gba
Ise na niyi
E ba mi wa
Efun
Osun abere
epo igi amuyan
Ikode kan
gun gbogbo e lotooto
Po gbogbo mo ose ko si Ike olomori fi ikode gun ose yen lori
Ma fi we larolaro pelu adura
a ba wa lara mu o
Fun alaye e pe number yi 08145707383

08/04/2024

OBIRIN TI OYUN NBAJE LARA E
mo ki wa ninu yara alayo yi pe a ku ojumo
adura wa a gba
Ise na re
ewe abamoda ti ko lu to po
Ewe efinrin to po die
Omi ajipon
fi omi ajipon gbo ewe mejeji yi papo dada
Se omi yen ma mu
Se be losu meta lera
oyun yen o ni baje mo lagbara olorun alaye
Fun alaye lori ise yi e pe number yi
08145707383

08/04/2024

FUN ENI TO NI ERAN IKORIRA LARA
mo ki wa ku ojumo ninu yara alayo yi
Ise na niyi
Ewe akoko oojo
Eku afe kan
Iye agbe kan
Iye aluko kan
fun po mo ose dudu
Ko si Ike funfun olomori
Ki okunrin we lojo mesan, ki obinrin we lojo meje
a ba wa Lara mu
Fun alaye lori ise yi e pe number yi
08145707383

05/04/2024

ORU INU(internal heat)
Mo ki wa ku ojumo ninu yara yi, ago ara wa o ni gbabode aisan, mo fe fun wa ni asiri yi
ISE NA RE
ewe ibere gbigbe
ewe cashew gbigbe
a ma se jona dada, a ma mu ni cup kan ni emeji lojumo, a ba wa lara mu, fun ibere lori ise yi e pe mi si 08145707383

05/04/2024

OGUN AISAN HYNEA
mo ki wa ninu yara yi ku ojumo, mo fe ki gbogbo wa je anfani asiri yi
ISE NA RE
ewe casia to po, a ma se pelu omi to mo dada, Mimu ni emeta lojumo glass cup kan, a ba wa lara mu fun ibere e pe mi si number yi 08145707383.

05/04/2024

ERO EFORI TULU
a ku ojumo aisan o ni se wa tomoromo lase olorun
mo fe fi asiri efori tulu yi sile fun wa
ISE NA RE
ewe soro
Aidan die
egbo tude idi kan
gun gbogbo re po, da si ona meji, po Ikan mo ose, po Ikeji mo ori, ma fi ose fo ori sinu gutter, ma fi ori yen pa ori yen a ba wa lara mu. Fun ibere e pe number yi 08145707383.

05/04/2024

Mo ki wa ninu yara alayo yi pe a ku ojumo, ojumo ayo,ire, owo, Ola, ati ifokanbale lo mo wa loni
ATUDE TO DAJU
mo fe fun wa ni asiri yi loni lati bo lowo ogun ide
ISE NA RE
oga gbigbe kan to pe
Igbin apinu kan ewe imi esu oojo
ewe ajeobale oojo
Odidi atare kan
a ma wa ape tuntun, a ma yo owo oja kuro Lara ape yi, a ma gbe sori aro wa, a ma ta epo yi aro wa ka, a wa ko gbogbo awon nkan ti a ko sile yi sinu ape wa, a ma jo leyina a ma lo kuna dada, a ma fi epo pupa la ebu yi lalale. a ba wa lara mu fun ibere tabi alaye lori ise yi e pe number yi 08145707383

05/04/2024

OGUN STROKE
a ku ojumo alayo ninu yara yi, olodumare o ni je ki aisan se gbogbo wa Amin ase,
Asiri ti mo fe fun wa Lon ni Isegun fun aisan stroke
ISE NA RE
Omi igbin ojuda to po die
Omi osan wewe niwonba
Oyin gidi niwonba
Alubosa ayu die
Atale pupa die
Iyere die
Kanafuru die
a ma gun gbogbo awon nkan wonyi po kuna dada, a ma wa da sinu omi igbin, oyin, ati omi osan wewe yen, a ma mu ni shot kan laro losan lale. a ba wa lara mu, fun ibere tabi alaye lori ise yi e pe number yi 08145707383.

03/04/2024

mo ki wa ku ojumo ninu yara alayo yi
ohun ti mo mu wa loni ni
ITOJU AKANDUN
ohun ti a nilo niwonyi fun eni ti akandun nda lamu
e ba mi wa
egbo gbegi
egbo alegunloko
Ewe imi esu
Ose dudu
e je ki a gun gbogbo awon Eroja yi kuna dada mo ose dudu, a ma fi ose dudu yi pa ibi ti akandun ti mu wa, a ma fi a*o to mo dada we owo wa. a ba wa lara mu fun ibere tabi alaye lori ise yi e
pe number yi 08145707383

Address

3 Kayode Adelokun, Off Governors Road, Ikotun
Lagos
10027

Telephone

+2348145707383

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Itoju Omode Agba Aboyun Itumo Ala Ati Ona Abayo Fun Won posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Itoju Omode Agba Aboyun Itumo Ala Ati Ona Abayo Fun Won:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram