
26/09/2023
EKASAN GBOGBO ILE EJEKA LO GBINYANJU ISE YI ODAJU OOO...
EWE OGBE ORI AKUKO
Bi opolopo awon eniyan se manpe ewe yi, Sugbon o tuni awon oruko min tonje. But ki o baleye eyin alakoye, eje ka pebe. Ewe yi je ewe to common gan but opolopo eniyan o Mon iwulo re. Iwulo ewe yin po gan, ibiti iwulo re pode, Aoma finse obe(soup), Ogun tun ni. But ma yonda die ninu ise e.
modarikan...
Eso(flower) ori e 7/9
Eyo Atare 7/9
Eko sinu Akara Kengbe, kie je leyin 3 days, Anybody toda saagun buruku siwa, Awa ni Ama je Akara oku eniyen.
ikiya & Ilaya
Ewa(beans)fufu
Eso ori ewe yi topo die
Ota sango.
Aogbe koko ijogun wa Lena, aoju ota sango yen sinu e, aoda Ewa lelori, aowa ko awon eso yi bomole, aofi omi si. Aoje toba ti jina. Aowa lo toju Ota sango yen di ojo imin.
ogun_ofa
Oju ologbo topo die
Eyo Atare topo
Eso ewe yi
Aoko Gbogbo e sinu otin, Aoma mu,
Aparun...
Ajeku ireke ti won tu sile, Odidi Atare 1, aojopo mo ewe yi, ao ma fimu eko gbigbona larolaro.
Ti o ba fe se ogun yi koje o san owo ajegun fun mi o je fun wa oo
TI EBA FE KI A BAYIN SE ISE YII?
°°TABI EFE IBEERE TABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI EDAJUKO . .PESORI NABA MI TABI KOBAMI SORO LORI WHATSAPP 09061671608 or 08147380143
IF YOU WANT TO ORDER MY PRODUCTS?
°° YOU HAVE ANY QUESTIONS ON WHAT WE POST
°° OR YOU NEED HELP ON ANY SPIRITUAL PROBLEM OR WAR THAT YOU ARE FACING CALL OR WhatsApp
09061671608 or 08147380143
......Ikilo warning
(1)mape min fun ibere tikoni itumon rara
(2)mawa lati toro asiri laini owo ajegun lowo oo
(3)mafi msg tabi call damu min ti obamon wipe oo serious rara
(4)ma flash number rara oo
(5) ti oba pemin ti min ooo pick ree lemeji daduro fun bi wakati kan
FUN EYIN FANS MI TIE BAFE FUNMI NI EBUN
ACCOUNT NUMBER MI RE:-
8106105889
PALMPAY
ACCOUNT