13/10/2024
ASIRI EKO ELEWE}
Eko elewe je okan gbogi lodo gbogbo awon alaajo sise nitori kose mani ni eko je,ona ti a ngbalo eko elewe pe orisirisi.eko elewe fun arare gan ogun ni loto lodo awon to molo bi awon baba alawo,hmm awon miran ninu awon babalawo amalo fun, etutu niyio figbe,elomi ebu ni yio filo,elomi saara niyio fise,ati bebelo,akiyesi eko elewe lodara ju lati ma filo ise eyikeyi, ise asiri bibo,asina,aanu, fun awa ti ankii lo oti lafi lo ise,
{DIE LARA AGBARA EKO ELEWE}
ao ra eko elewe Kan ao bo ewe kuro Lara re,ao fi blade tuntun la lati oke de isale ni gbooro,ao fi blade ge abala eyokan ninu eko yi si meta ao ki eso werenjeje ati omo atare kookan bo inu eko tia la si meta yen. Ao ma gbemi ao ni je o lilomi ni okookan. Walai bi enikan baleri siwa wipe ohun yio pawa ti ise imule yi bati wa Lara wa walai enina niyio ku dipo. Koda ko ni ogun ju aroni lo ayafi koma sasiwa ,ao so ilaji eko toku na nu tewetewe ,,ale lo fun omo odun mewa fun protection ,,asiri TAPA todaju ni.
2. Eniti awon Alfa ,woli tabi awon adifala ni iyare lo nse tiko fi ri ona lo
Ki iru enibe lo ra eko elewe meji kio kio ko lo fun iyare kio be iyare dada kio wa bo sofun iya pe kiwon se adua si ara eko elewe mejeji ni ihoho omoluabi ki iya je eko Kan ,ki omo na je eyokan toku... inshallah tobajepe otito niwipe iyare lo nse o pelu ogo olohun ona yio si fun o,Toba tun wu omo na ole ra bi a*o ati nkan miran pelu
Eko elewe Kia bo ewe larare Kia bu epo oyin iyo die lelori Kia se adua si Kia gbe tewetewe losi oju ona ti ese o rinmo hmm asina ni
Ejekia dake loni Toba di ojo iwaju ao ma tesiwaju.
Gbogbo enito ba fe ko ise yi tabi tofe se screenshot ise yi gbodo comment kobale je bina ko ran bi orun.
Awon baba wa nile Yoruba ninu Oro pe,asiri eko kiitu loju ewe, gbogbo eniyan to n fi owo alubarika re se Amin adua yi,asiri re koni tun lagbara Olọhun,amin
FUN ALAYE LEKUN RERE LORI ISE ASIRI WONYI
IBANISOROMI 07063768873 or 09135720973