Iseselagba fun omokarojire

Iseselagba fun omokarojire For all kind for spiritual help,Oracle consulting, Traditional healing from illness like stroke, epil

Ibaje eniyan ko da ise olohun duro
05/05/2024

Ibaje eniyan ko da ise olohun duro

Aseje asiri bibo todajuEwe efinrin gidi ojo 16, ponmo ti won sun, a o ge so 16, Omo atara 16, iyere 16, Ata ijosi 16 ATI...
05/05/2024

Aseje asiri bibo todaju

Ewe efinrin gidi ojo 16, ponmo ti won sun, a o ge so 16, Omo atara 16, iyere 16, Ata ijosi 16 ATI Ewe ola

A o lo awo aroja won yio lotootoo, a o fi se ponmo yi lepo niyo ninu isasun tuntun.
Ao so aseje yii so ori osuka tio ba ti jinna
Ao se adura sii daadaa
Ao koje ni gbigbona

Contact me for any request or questions

05/05/2024

Back to Nigeria

18/08/2023

A o Se ewe eyin olobe pelu ewe owuro ti yio jina
A o ma mu agbo yi
Agbo Yii sise fun IBA

18/08/2023

Ogun Asiri bibo
Ewe tanapaje
Ewe sawerepepe
Odidi atare kan
Aojopo
A le fi oti, oyin tabi omi lo

Ekaro Gbogbo IleEyo atare 2...!Werenjeje 2...!Owo eyo 2...!Ao da otile Lori Ao ni je ki o Kanle
14/08/2023

Ekaro Gbogbo Ile
Eyo atare 2...!
Werenjeje 2...!
Owo eyo 2...!
Ao da otile Lori
Ao ni je ki o Kanle

30/07/2023

Happy Sunday
A ku ojo isimi

03/01/2023
03/01/2023

Ipara Anu
A o wa eso rerinkomi, odidi atare kan, Eyin ororo ati turari sudan
Ao yo gbogbo omo atare ti ko gbo do din, ao lo mo ewe yii, ao wa po mo eyin, a o wa sa si inu Ile laisi orun fun ojo meta, ao wa tun lo ti yio kunna, a o PO mo turari Sudan yii, ao mo fi pa oju, owo, ati ese, ti a ba ti jade

03/01/2023

Happy new year to my fan here
It’s been a long time
May we live long to reap our effort

A ku opin ose, a o ri aje jeun oooE je ki a se ise yii soAo waOmudo ewe iyalode fun funOmudo ewe amenudunEwe eyin lobeEg...
06/08/2022

A ku opin ose, a o ri aje jeun ooo
E je ki a se ise yii so
Ao wa
Omudo ewe iyalode fun fun
Omudo ewe amenudun
Ewe eyin lobe
Egbo iyalode fun fun ATI pupa
Ao gun gbogbo re to yio kunna
Ao po mo ose dudu
Ao ko ose yii si Inu Ike fun fun
Ao ma Fi we ni alale ti aba Fe sun
Ao Fi epo pupa pa gbogbo Ara ki a to we ose yii

30/07/2022

Mo ju ba olodumare, mo ju ba awon olodumare gbe Ile aye Le lowo, mo ju ba eni ti o Koko ja ewe, mo ju ba eni ti o Koko WA egbo.
E mo je ki o hun mi
E je ki o ma ju mi se.
Asiri BIBO/Tude
Ao WA eyin ororo 3 pelu opolopo ewe eyin olobe.
Ao Fi ewe tele isasun
Ao WA ko awon eyin yii sii
Ao tun ko ewe Yi Le eyin Yi
Ao WA gbe ka na ti yio Fi jina awon eyin Lai Fi Omi si
Ao ri dajupe asale ni a se ise yii
Ao je eyin
Ao da awon idoti yoku nu
Ao losun Lai jade mo

Send a message to learn more

Address

Ogbomoso

Telephone

+2347025438624

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iseselagba fun omokarojire posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share