JAGUN Trado Medical CARE

JAGUN Trado Medical CARE Help people to soft there problem with ( ewe ati egbo & ifa) any kind of problem you have call +234

Jagun Trado Medical Care on whatsApp (+2348103544510).If you are interested you can call.jagun Trado Medical Care for your problem to be sove,(+2348103544510).....

28/09/2021

JAGUN Trado Medical CAREOGUN OSHOLE. OYE ALAGEMO KAN (OGA) OWO TI A'NA TITUN KAN BERE LAT #500 OTI DRY GIN KAN EAGLE,LORD TABI OTI MI TI OLE DAADA.,IKE FUN,FUN KAN TABI AWO FUNFUN KAN. EWE AWEREPEPE OOJO, EWE ABAMODA OOJO EWE ALUPAIDA OOJO. SISE RE. A MU OGA YEN SINU IKE FUNFUN ATI OWO TITUN YEN A WA LO JA EWE ABOMODA A FI OTI YEN GBO AWA YO SAFUSAFU DANU A WA DA OTI YEN LE OGA YEN I LORI NINU IKE AO GBE SI KONKO OGIRI ILE WA FUN 21 DAY IJO MOKANLELOGUN TI AYIE BAWA ALE RIN ISE YI MOLE SI IKORITA META TI IJO YEN BATI PE AAYO OTI SINU IGO PADA AWA LO JA AWON EWE TI OKU ATI ABAMODA NA JIJO NI PELU ATARE ODINDIKAN A RO EBU RE SINU OTI TI AYO YEN AO MA MU GASI KANKAN LARO KI ATO JADE NILE ODAJU. AO MA DABA IYE TI ABA FE LOJUMO LO SI IDI ORO AJE WA NI DAN WO KI O FUN ILE LABO. N,B FUN ALAYE 08103544510 OLODE ANU DUPE KI O BA LE JE FUN E OLORUN ALOWO SI
jagun trado medical care
08103544510

27/04/2021

OGUN OSHOLE. OYE ALAGEMO KAN (OGA) OWO TI A'NA TITUN KAN BERE LAT #500 OTI DRY GIN KAN EAGLE,LORD TABI OTI MI TI OLE DAADA.,IKE FUN,FUN KAN TABI AWO FUNFUN KAN. EWE AWEREPEPE OOJO, EWE ABAMODA OOJO EWE ALUPAIDA OOJO. SISE RE. A MU OGA YEN SINU IKE FUNFUN ATI OWO TITUN YEN A WA LO JA EWE ABOMODA A FI OTI YEN GBO AWA YO SAFUSAFU DANU A WA DA OTI YEN LE OGA YEN I LORI NINU IKE AO GBE SI KONKO OGIRI ILE WA FUN 21 DAY IJO MOKANLELOGUN TI AYIE BAWA ALE RIN ISE YI MOLE SI IKORITA META TI IJO YEN BATI PE AAYO OTI SINU IGO PADA AWA LO JA AWON EWE TI OKU ATI ABAMODA NA JIJO NI PELU ATARE ODINDI KAN A RO EBU RE SINU OTI TI AYO YEN AO MA MU GASI KANKAN LARO KI ATO JADE NILE ODAJU. AO MA DABA IYE TI ABA FE LOJUMO LO SI IDI ORO AJE WA NI DAN WO KI O FUN ILE LABO. N,B FUN ALAYE 08103544510 OLODE ANU DUPE KI O BA LE JE FUN E OLORUN ALOWO SI

ASINA AKARABITIAlagba adanripon meta...togbo daadaOwo eyo tiko luju metaAtare nla  metaEwe ewuro oojo Sise reAo ki owo e...
17/04/2021

ASINA AKARABITI

Alagba adanripon meta...togbo daada

Owo eyo tiko luju meta

Atare nla meta

Ewe ewuro oojo

Sise re
Ao ki owo eyo tikoluju yii sinu alangba yen nikooka sinu re

Ao ko ori re si arawon ninu ikooko..ao ko atare yen sinu re...ao ko ewe ewuro sinu re ti o bomole daada

Ao wa jopo daada...ao loo ti o kunna daada

LILO ISE YII
Ao fo eko sinu abo kan...ni ago mejila oru ..ao da die ninu ebu yii si atelewo wa

Ao se adua siii...daada
Ao dasinu eko yen...ao gbemu leekona

Ao loo ise yii fun 7days ti ko gbodo jaa
JAGUN Trado Medical CARE
08103544510

ASINA AKARABITIAlagba adanripon meta...togbo daadaOwo eyo tiko luju metaAtare nla  metaEwe ewuro oojo Sise reAo ki owo e...
17/04/2021

ASINA AKARABITI

Alagba adanripon meta...togbo daada

Owo eyo tiko luju meta

Atare nla meta

Ewe ewuro oojo

Sise re
Ao ki owo eyo tikoluju yii sinu alangba yen nikooka sinu re

Ao ko ori re si arawon ninu ikooko..ao ko atare yen sinu re...ao ko ewe ewuro sinu re ti o bomole daada

Ao wa jopo daada...ao loo ti o kunna daada

LILO ISE YII
Ao fo eko sinu abo kan...ni ago mejila oru ..ao da die ninu ebu yii si atelewo wa

Ao se adua siii...daada
Ao dasinu eko yen...ao gbemu leekona
Ao loo ise yii fun 7days ti ko gbodo jaa

JAGUN Trado Medical CARE
08103544510

17/04/2021

, e ku ojo meta, e ku airini beere eni, e ku atilo awe, emi wa yio reyin osu o.
ASIRI OWO BIBO LAARIN OSE KAN.
A o wa Okete aaye kan, a o la ni aya de ile, inu agbada ni a ma gbe si, ki eje re maba ta danu, a o wa fi eyin re lele ninu agbada yen ti aba ti la tan, a o wa fi ori oka to lase lenu kan si ninu pelu odidi atare kan. A o jo po, a o lo kuna, a o di si ona 16. A o wa omi agbon topo die, a o ro pamo sinu ibikan, a o mafi omi agbon yen lo ebu yen fun 8days.
NOTE 1 Fun eni ti kogba awe, Ago kan oru ati ago kan osan ni lilo re. Fun apeere, ti a bajo ise yen ni osan tabi irole tabi ale oni, a o bere lilo re ni ago kan oru ola thursday, a tun ma lo omiran ni ago kan osan thursday na. Emeji lojumo loma je. Fun Muslim, Irole ti aba koko sinu tan ati idaji ki ato jeun ni lilo re fun muslim. O maje emeeji lojumo, aaro ati ale. Ojo mejo ni e fi ma lo.
NOTE 2. Ojo monday tabi thursday ni o dara lati beere re.
NOTE 3. Eyan kan lowa fun o.
NOTE 4. A ko gbodo ni ibalopo fun odidi 14 days, bere ni ojo ti a start ogun na. Ise todaju ni.
ISE AANU TI AFI N PADE ALANU.
A o fi oti lord gbo ewe orijin oojo ati ajeobale oojo, a o tu milk olope kan si, a o ma mun ni araro kutu hai, ki a to soro siyan.
Sadura funmi ki o bale je fun o.
JAGUN Trado Medical CARE
08103544510

Mo fi ''ISE EYONU AWON AGBA'' yi sile nitori ojo ibi mi to lona loseyi ( my birthday gift )fun awon Eyan ti won N sise b...
06/01/2021

Mo fi ''ISE EYONU AWON AGBA'' yi sile nitori ojo ibi mi to lona loseyi ( my birthday gift )fun awon Eyan ti won N sise bi Erin ti won Nje Ije Eliri. Awon Eyan ti won ko ri Alaanu ti o ma ran won lowo. Eni ti o ti so Ireti nu.

Akiyesi Pataki:- ISE EYONU AWON AGBA lo ye ki awon Eyan ma lo ni gbogbo igba. Bi eyan ba mo PRESIDENT, GOVERNOR, OBA ati awon Eyan Nlanla, bi ko ba si EYONU TO TODAJU lara Eyan, won ko ni ran Onitohun lowo. Koda won a Korira Onitohun.
E lo dan ''EYONU AWON AGBA'' yi wo, Ki e fun Ile ni Abo.

Akiyesi Pataki:- E koko lo se ISE AJEGUN yi naa, Ki e to bere sini maa lo Awon ISE EYONU naa. (AJEGUN TODAJU)- Ewe Ejinrin tutu Oojo, A o fi Omi Agbon pupo gbo Ewe Ejinrin naa papo daadaa, E o yo Omi re sinu Igo funfun kan. E o maa mu omi naa diedie, Ajegun yi a je ki gbogbo ISE AAJO ti e ba nse tete ma dahun ni kiakia.

(OSE EYONU AWON AGBA TODAJU 100% Guarantee)-
Ewe Ajeobale tutu Oojo, Omunu ewe Ewuro tutu Oojo, Epo-Obo, Kafura pelebe, Eru Alamo, E o gun gbogbo re papo mo Ose Aganyin tabi Ose dudu ninu Odo Ko kuna daadaa. E o fi Omi Agbon po Ose naa papo daadaa. e o ko Ose naa sinu Ike funfun olomori. E o ma fi Ose naa we ni gbogbo igba laarolaaro.

OSOLE IMONIYAN
Ewe ejinrin aosu losuka SINU ape AOGBE ori olongbo tonirun le aoto owo EYO 21 yikare AOGBE atare kanle AOJO aoda sona merindinlogun AOMA fi omi alujonu tole lo LARARO.
Fun iwo to ba fee fun mi ebun ojoibi birthday gift send the money to
my account first bank
3063078676 adeniyi odunayo samuel

( Fun ibeere message me on WhatsApp 08103544510)
JAGUN Trado Medical CARE

06/10/2020

( WARI TIE MU NIBE )

OGUN ASETO
Ogede omini ao ge wewe sinu ike olomori ao fi ako kohun si ao bu omi tutu si ao ma my die die

OGUN IJU
Enuopire epo ogede agbagba dudu ifun abo adie ako kohun ao Jo po ao mafi oti oyinbo lo laro laro

OGUN OGBE INU ULCER
Egbo tinupogbe ipeire eru awoka odidi atare ao Jo po ewedu ti ko si iyo nbe ni ao ma fi lo odaju gan

OROBO IDI YIYO
igbe maalu tutu pipo mose ao mafi ti idi naa sinu

HYPERTENSION ( EJE RIRU)
Epo pandoro eru Alamo egbo ipeta egbo asofeyeje gige so wewe poroporo ao gun ao kunna dada ao da gbogbo e sinu omi osan wewe mimu die die

TI EPON ENIYAN BAN SA WOLE
Ao lo opolopo orogbo gbigbe ati abere gbigbe yio jao dogba dogba ( ike ) ao da sinu oti oyinbo mimu ni gass 1 laro epon re yio pada bo sipo

OSE ARA TITA
Epo ara asofeyeje epo obo die iyere die ao gun mose ao mafi we yio lo

IKO ASTHMA
Ewe omisinmisin iyere ata ijosi ao po ao da sinu oyin ao mala die die

OGUN ITO SUGAR
Ao Loja ewe ewuro oojo ao gbo pelu omi osan wewe ao mamu ni gass cup kankan ni aro ati ale koju beelo

IDI TON YO
Ewe agogo igun eso werenjeje kahun bilala die ao lo kuna ao ma fi shinapp lo

OFUN DUNDUN
Ota inu iroko atare ao gun po sinu oti ao mamu die die

EPON APAKAN TO WU
Epo amuyan eru awoka ao se pelu omidun ao ma yo die die mu

TI ENIYAN BAN TOJU
Igbe adie ao lo kuna pelu ewe egungun eja ao lo mejeji kuna dada ao ma fi foko me die die

OSE AWOKA
Ojele (irele) ewe p**i ao lo pelu ose dudu ao ma fi we ese naa walahi odaju gan

AGBO INU RIRU GBOGBO NISE
Bara epa ikun baka epo amuyon epo sapo ao se pelu omidun ao ma mu die die odara gan

AGBO ARAN TIN DAMU ENIYAN GAN
Egbo eruju egbo ijon egbo botuje ayidan alubosa elewe ao da ni agbo tutu ao ma mu ni ojo keta keta laro laro

ONJE OJU ORUN
Eku asin tutu ao ge wewe sinu ike kan ao da adi dudu si taba dojo keta yio ma mu sibi kankan

EYIN DIDUN (back pain)
Epo igi arere eru kohun ao re sinu omi ao ma
O

Olohun konifi aisan se wa oooooo.....

Jagun Trado Medical Care
08103544510

04/10/2020


ise na niyi 👉👉

I I I I
I I
I I I I
I I
#

#

(1) Okan malu funfun eyokan
(2) iye agbe meta
(3) iye aluko meta
(4) iko odide meta
(5) eso ewe Sefun Sefun
(6) Omoonigedegede
(7) iye leke leke meta
(8) iyere ni wonba die
(9) omi Okun
(10) Pepe/ohun ni efon ope

#

Ao lo gbogbo inkan ti adaruko yi papo mon ara won ao wa fi se okan malu na je lepo niyo Pepe yen ni ao fi ma ro ni ori ina omi Okun lao fi se obe na

#
Ti obe yi ba jinna tan ao so ka ibikan ti oba ga tori wipe idi obe yi ko gbodo kanle mon leyin ti aba ti se tan ti Oti tutu niwon ba dieee ao da enu ko obeyi ao bere sini pe gbolohun re si ao juba olodutomare ao juba awon ti oni ile aye oooo

..... HA! HAA!! HAAA!!! # 3*

I I I I
I I
I I I I
I I
#

Larin eye lolodumare ti daro fun agbe larin eye lolodunare ti kun aluko losun larin eye ni olodumare ti kun leke leke lefun larin eye ni olodumare ti ki ikode bo epo pupa ti fi ngbayi lawujo eye, lawujo omi ni olodumare ti fi Okun se olori omi, larin agbo malu ni fun fun tin gbayi. OWO nla nla lafi ra malu aki ridi Okun aki ridi omoni gedegede lati kekere ni Sefun Sefun tin so aje tire ki emi lagbaja Omo lagbaja mori ire aje temi lati onilo ati t**i lai lai amin ao se opolopo adua si ki ato bere sinije

(1)_AKIYESI_AKO_KO #
Eso Sefun Sefun ni ao lo ti ao fi te ifa ofun meji sinu awo fun fun perese kan ki ato wa da si inu obeyi ki atun to wa pe paapo ao wa bere sini je obeyi lati dede agogo Merin idaji
(start eating the concurtion from 4:00am in the morning till 5:00am in the same morning)
Lati agogo Merin idaji ojokeji t**i di agogo marun aro

(2)_AKIYESI_ELEKEJI .....
ao se obeyi ni ale ao bere jijere ni ojo keji lati ago Merin idaji ni aro di ago go marun ki ato parire hmmmmm ao mun omi airi le lori ti abaje tan
Ti aba ti je obeyi tan ao sare jade kuro nile lo si ibi ti ojin na si ilewa bi wakati meji (2hours) later ki ato pada wa si ile wa pada
Hmmmm leyin (15days) ogun na yio bere ise owode onasi ona la
After (15th days) this work started working and bring alot of money
Notice ao gbodo summon obinrin fun osukan ati ose kan
should not have s*x with woman after we eat this concortion for good one month one week just take note for this

Who Is Sango?The true and genuine answer to the questions who is Sango cannot be answer without throwing muds to certain...
06/08/2020

Who Is Sango?

The true and genuine answer to the questions who is Sango cannot be answer without throwing muds to certain existing widely accepted distorted myths for hundreds of years in Yoruba land. It will also offend some town that have made even the Sango worship and practice popular. But the truth needs to be reveals. In Yoruba Ifa cosmology, Sango is believed to be one of the Irunmole that descended from heaven to earth. Sango is not an Orisa (Saints). Sango is a is Irunmole (celestial beings). In Ifa cosmology Irunmonle are not born of Human beings.No body no of their parents such mother or father. The only things known about them is that Olodumare delegate them to come to this world to perform one mission or the other. Example of Irunmonle are : Obatala, Orunmila ,of course Esu Odara too is an Irunmole. While Orisa are Human being turn divinity. They are they human being that have extra ordinary sterling qualities and do extra ordinary thing in life and when they died or vanished they will be defied . It is those who undergoes posthumous deification that is known as Orisa in Ifa theology. They are born of human being, we known of their parent ,their father etc. From the forgoing illustration, Can I start to shake the table? I think I need to. The first point is that even Oyo town remains spiritual headquarter For Sango worship till today. The real Sango is not from Oyo. The third Alafin of Oyo that adopt Sango as name is not the Original owner of that name . He usurp the name . As at today many Babalawo even here In Yoruba land that ought to known better did not known that when ever Ifa stanza is talking about Sango . It is not talking about the popular Sango who is the Alaafin Of Oyo that is deify as Orisa . It is taking of Sango Irunmonle. My position and argument is this In Yoruba Cosmology We have two Sango. One is Sango Irunmonle (which is been refer in Ifa scriptures) and other Sango Orisa (which is human being like me and you turn deity- That is the one that is been worship today , the worship start in Oyo . I will explain everything soon and how it started , including how you can make one for yourself if you want to. )Yes I have come, I know some of you have been raise on falsehood with this lies and distorted myth and history , and some of you known the truth but you are afraid of thrones. All power belongs to the creator the giver and taker of life.
Sango Irunmole
Sango Irunmole is the one of the contemporary of Obatala,Orunmila Esu Odara That descended from heaven to earth . Have it at the back of you of mind that Sango (I mean the third Alaafin Of Oyo who rule Oyo between C 1252 which historically fall withing the range of 13th century (the second millennium). He can not be regarded as contemporary of Obatala, Orunmila, Esu Odara. Those being are spiritual and they are having been out of physical existence by this time that this third Alaafin of Oyo rule in 13 century. Base on this premises Sango the third Alaafin of Oyo is not the first owner of that name and also he can not be regarded as Irunnmole (celestial being) he is an Orisa (a saint).
Now that I have been able to prove to you that Sango ( the first one who is Irunmonle exist before the reign of third Alaafin of Oyo). As elucidate in Ifa scriptures Ifa make it clear that Sango ( I mean the Original Sango which is Irunmole ) get mandate from Olodumare (God) to be in charge of: Rain,lightining and thunder ,Fire. In Ifa cosmology . It was believed that whenever human race have any issue related to this aforementioned it Sango they should approach. Odu Ifa Ofuntola which is also known as Odu Ifa Ofun Oturupon make us known Sango have sphere of influence over rain.
II II
I II
II I
I II
Oturupon Ofun says:
Ese kan soso ni mo ti bo Egan
Igba Eke ni mo sa jade
Dia Fun Sango
Ti Olodumare fun ni Ado ase ko ma fi Ojo se omo Araye lore
Ttranslation
It is just one legs I put inside the forest
It is two hundred of rafters I brought out
This was Ifa’s message for Sango
That Olodumare gifted with Ado Ase to be blessing the people of the world with rain.
Ifa Ifa cosmology it believe that when all Irunmone is coming from heaven to earth . The ride on some of the Odu Ifa as their compass. The compass for Sango Irunmonle is Okaran meji .
II II
II II
II II
I I
When Sango Irunmole was on earth, Myth have it that he wear red color cloth , he eat a lot of bitter kola . he drinks. He easily gets angry. He is fierce in looks. They say he eat Amala and Gbegiri . That is what they said I don’t live then. During his time, He hate Hypocrisy, stealing, robbery or any form of illicit behavior. Have natural power to use thunder to punish offenders . I probe furthers to know what end him . Up till now I was unbale to get any living who proffers answer to how Sango Irunmole turn back to heaven or which town he lives during his life. After his demise. History have that many people do incarnate as him by exhibiting his traits and characters.
Sango Orisa
Sango Orisa is the third Alaafin of Oyo . he is human being; he is born of human. He is one of the human figure that is re-incarnated as Sango. Historically his mother is from Tapa. And history have it the Elempe Of Tampa give one of his beautiful daughter known as Torosi in Marriage to Oranmiyan as peace treaty. Though some oral tradit**ion in Oyo town dispute the name , those who dispute this name claims that the name of Sango mother that was Marry to Oranmiyan then is Omotoyosi. Wether the Name of Sango (Sango Orisa) is Torosi or Omotoyis is immaterial . The point to prove is that he have mother. He was gave brth like you and me. In fact her mother give bath to Ajaka before him. And is name was not even known as Sango from the beginning. Some say his actual name his Tella oko, some say it is simply Tella that Oko is not there . In this work I will stick with Tella. According to Oral tradition when Tela mother (torosi/Omotoyosi) was pregnant with her second child. Whenver she goes out in the night where the is darkness he will sense that the will be sounless ligtning that will bright her path as everywhere will become clear .This occur times without numbers put her in fear . This is what promt Her and her husband to invite an Awo to make Ifa consultaion for them to ascertain what is going on, in the course of the Ifa consultaion Odu Ifa Okanran Meji was reveal . The Awo told them that the child that woman is carrying in her stomack is powerful chilld that is going to be famous arpund the globe. They were Advise to venrete Sango Irunmole for him. So her mother normaly venerate Sango with yam flour foods and Amala and Gbegiri untill Tella is born.
On the day of delivery of Tella , he was given birth during dry season. It is not expected that rain will fall. It was claimed by the elders who handle down this history that rainfall and that there is incessant thunder strike and lighthinig. When the child is is born his left hand is tightly folded. And his unblical cords was tightly wraped around all over his body and to big for one child. The parent call The Awo again to divine for them to ascertain what to do. The Awo Make Ifa consultaion and davsies them to offer ebo and venerate Sango. That the mother of the baby should cover her body with Red color cloth and also cover the baby with red color cloth. They allow the baby to roll in his bath blood . They should Equally venerate Sango . which they did . Tella finaly open his hand nad inisde it was wa one Edun Ara ( sango scared stone) . The umblical cord was also removed. They name the babay Tella and Afonja. Some say Tella is derived from the habit of forcifully try to open left hand at birth Te la (to be force to Open) while Afonja is derive from that which will try pull without getting severe. Wether this is the actual meaning of this names I can say. That is what pass on to us.The Edun Ara was kept for Him. He was made to become devotee of Sango. So tella which people deiffy and worship as Sango today is a devote of Sango himself. It after his death that his follower deify him as deity.
When Tella grow up he choose acrobatict display and muisc and druming as profession. He aproach the powerful Awo to prepare charms of various sort for him. He become extremely talented and powerful in the act of Magic. Be become an astute magician.he can dis apper and re appera and also walked on on air, emitt fire in his mouth at will.
But all these various account whether myth or historical prove that Sango elder brother is Dada known as Ajaka. This Ajaka is said to be a weakling and extremely timid individual as oppose to his younger brother Sango who is extremely brave and powerful. From all the historical account available it prove that Sango is the one that dethrone his elder brother Ajaka as second Alaafin Of Oyo. This incidence give rise to How Sango Become the third Alafin Of Oyo.

Sango was a very fierce and versatile magician. He does emit fire and smoke in the mouth to enhance his dancing trade. Sango act of bravery and power come to lime light when Oyo was under the servitude of Olowu during the reign of his weakling brother Ajaka as Alaafin Of Oyo Empire.It was Sango who was able to wage war against Owu and liberate Oyo from the captivity of Owua and even able to bring other twon in Yoruba land under dominace of old Oyo empire.This lead to forceful dethronement of Ajaka And how Sango become third Alafia Of Oyo. Sango was a revered King, all his subject respects him not because he is a king. But he is extra ordinarily brave and powerful both physically and in act of magic.
It is after his death that he was deify as Orisa. Let succinctly peruse the historical account Of Sango death. Though there are various historical accounts on Sango death. Some school of thought in tradition said that Timi and Gbonka who are two powerful warrior that serve under Sango that force Sango to abdicate the throne and commit su***de. With due respect this school of thought is wrong based on the preponderance of account available about Sango. However the seemly most valid account about Sango death is the one that claim Sango in attempt to test and reaffirm his magical power of emitting fire he accidentally burnt down his palace which lead to loss of his wives ,children and properties. This make some of his follower to flee from on him .It is only his Bata drummer that remain dedicated and follow him when he left Oyo in attempt to found another city. But history has it that when he got to certain Ayan tree .He hangs himself.
The prevalent story about Sango death is su***de by hanging. Though after his death his follower gather to practice their trade and whosever try to abuse them that Sango hanged himself. They will through magical preparation that Sango do use during his life time to strike such household with thunder. The people then begin to say Sango Oba koso to avoid the wrath of Sango follower who have the spiritual know how on how to send thunder to strike enemies. History have it that during the lifetime of Sango his follower and disciple that practice magic and lightening after his death did not have access to this secret knowledge. They need to go back to Ibariba Land where Sango’s mother Torosi hail from to learn how to make preparation that they can use to make thunder to strike the enemies who abuse them that their leaders Sango hang himself to death. After they have strike such house with lightening and thunder. The occupant of such house will need to offer varieties of sacrificial items, because Sango followers will go to such house and tell them it is because they abuse and repeat the story of hanging about Sango that is what make Sango to strike them. They will compel them to offer many items to prevent further anger of Sango and that they must stop repeating the story hanging of Sango. That is how Sango earn his nickname Oba-koso (a king that did not hang) after his death. If you want to know how to send thunder to enemies, You can read Babalawo Obanifa previous work on how to send Sango on Errand. It is true that Sango devotee often denied the su***de of Sango up till today. But the fact remain that Sango actually commit su***de
The Deification of Sango As Orisa.
As I explain at the beginning of this work. Sango is one of the personality in Yoruba Land that undergo posthumous deification. There are some school of thought In Yoruba tradition that believe that Sango was deify as Orisa to redeem his image of hanging himself to death or In some circle they claim the deification of Sango is to prevent and stop wide circulation news about his su***de. I totally disagree with these schools of thought and those who share such view. I do this with reason. The reason is simple:
If Sango did not commit su***de he will still be deify as Orisa because every person who ascend the throne of Alaafin Of Oyo have always undergo posthumous deification Sango case would not have be an exception. Up till the time I am writing this work If You Visit Alaafin Of Oyo Palace you will see shrines dedicated to all the previous King Of Oyo starting from Oramiyan,Ajaka,Aganju,Sango,Alaafin Aole,Alaafin Abidoun. Because the Oyo people view Alaafin As A representative of Olodumare(God)on earth.

The Uniqueness of Sango Deification As Orisa

There are some unique things about Sango. Sango deification is a bit more different and unique from the way other Alaafin are deified. Other Alafin that are Deify are only worship in the Palace of Alaafin of Oyo as Orisa by the descendants of such king alone as their ancestor. None of them is associated with any natural phenomenon. But Sango on its own is associated with natural phenomenon which expand his scope of worship and followers beyond Oyo palace even beyond Yoruba land. The phenomenon that Sango is associated with is lightning and thunder, because the myth about Sango give credence to the association of Sango with this natural phenomenon. During life time of Sango, Sango is said to be a powerful magician who do emit fire and smoke from his mouth when he spoke .He is said to be an expert in how to attract thunder and lightning and cause it to strike human being are his enemies or other human habitation. As I said earlier non among his follower during his lifetime have knowledge of this power. They need to go to Nupe land to learn about how to make this preparation .When they come back to Oyo lightening was striking the houses of those who repeated the story of Sango’s hanging. Each time thunder struck such house Sango ‘s follower will go there and claim the lightning’s struck indicate Sango’s anger against the lair that claim Sango hang himself to death when he was alive. They will tell them Sango is now in heaven angry about such abuse. That is while it struck the house with lightening. They will tell those who live in that house to offer varieties of item which can usually cost them a lot of resources that can cost them the house itself. That is how people stop abusing Followers’ of Sango about the hanging of Sango till today. With due respect to those who may concern Of this documentaries is not try to belittle the follower of any deities rather than we are trying to document and preserve the undiluted version of fact about all these deities for future generation.All my documentaries are from impartial perspective.

It is instructive that there are other deity that is associated with lightning and thunder before Sango. The name of this deity is called Jakuta. Jakuta is not an Orisa like Sango.Jakuta is an Irunmole. Sango is human being turn deity. Jakuta is not an human being. Jakuta fall into category of spiritual entity like Obatala, Orunmila ete. That descend from heaven that are not born of human.Jakuta is believe to be a spirit in control of the wind and lightening and thunder and he has the ability to thrown stone using the power of the wind. Hence he was given the name Jakuta. Jakuta simply mean one who fights with stones. In Yoruba culture and spirituality we have five days in the week. Each of these days was dedicated to worship of certain Orisa and Irunmole. It is the third day of the week that we refer to as Ojo Jakuta(Jakuta’s day) . Jakuta’s day is the third day of the week that is dedicated to the worship of Orisa Jakuta.Jakuta is believe to be gentle and kind spiritual forces. Despite the fact that it represent lightning and thunder.Jakuta never exercise any act of malevolence force of using lightening and thunder to strike anybody, evidence abounds that people pray to Jakuta for procreation . But with the coming of Sango Worship. Sango took over this day of the week from Jakuta the original owner. In fact Sango as a deity usurp all the function and privilege that has been hitherto accorded to Jakuta.
How Sango Usurp Jakuta Roles
Sango himself would have be worshiping Jakuta, been the only deity available that is associated with the lightning and thunder. But Jakuta is too meek and kind deity. Jakuta did not exercise a single control over lightning and thunder. But with the coming of Sango, Sango was a very ruthless being who was able to exercise control over lightening and thunder and practices it to the knowledge of everyone how he can use it to strike anything he want. People fear him than Jakuta. Hence his domineering over the Jakuta.The day that was previous allocated to Jakuta which is the third day of the week people now uses it to worship Sango. Sango and Jakuta are different deities even though some Babalawo and Orisa devotees do think Sango mean the same thing as Jakuta. But it is two different things.
Any types of spiritual attack,bad dreams and badly in need of pregnancy.We are here to heal you any kind of sickness problem you're facing improvement and financial problem..etc
©️ Jagun trado medical care
+2348103544510 whatsapp
+2347082225467 mobile

06/08/2020

*(OSE AGBELEPOTA TIKO NI ERO)* MOFI ELEYI KALE FUN
GBOGBO AWONTI WON GBA IBERE MI ELEYI NI ADEHUN
TIMO SE, GEGEBI MOSESO WIPE EMI KIFI ENU LASAN
ROYIN OGUN AFI TI ABA DANWO NA HUMM AWATI
OLOHUN BANI KIA RI ISEYI SE SI INU ILE HAAA WALAHI
EYAN TIDI APATA TI EYIN LASAN KOGBODO FI ORI LASAN
SO ISEYI BURU PUPO DEBI WIPE INA KOMA OJU ENITI
ODA OOO ISENA LOBAYI WIPE:-
ao wa eyele funfun aye kan ati ako alangba ti apa ni oojo
funrawa pelu abere oporo 201, ao wamu eyele aye yen ao
mafi abere yen gun ni idi t**i yofi ku toba jepe 50 tabi 60 lafi
gun nidi tofi ku tabi jubelo toba tiku ao wa fi sinu agbada ao
wa mu gbogbo abere yoku ao fi gun gbogbo ara alangba
yen tan pata ao wa fi alangba na si ori eyele yen ninu
agbada ao fi odidi atare kan si legbe ao wajo gbogbo repo
tia ban jo lowo ao mafi ata ijosi konare tia ba jotan ao lo
tiyo kuna dada ao wako awon abere yen ni ikokan ao fi
gbogbo ebu ogun yen po ose ao tiko koko fi omi de ose yen
kia to kia to fi ebu yen po tia ba potan ao wako ose yen sinu
ike funfun ao wafi abere yen gun oseyen lori ni ikokan ao
wama fi ose yen we ni alale tia ba fesun ni ekokan tabi
ekan ni ose.
---------------------------------------------
*NOTE*:
ti aba ri eniti aye banda lamu ju kio lo se iseyi ki enina
siwe oseyi fun odidi ojo meje whalai kio to di ojo keje
gbogbo eniti kojawo ni orore niyo ri inira laye tiyo sifi aye le
fun Iwo kojubelo.
---------------------------------------------
*NB*:- akilo
iseyi funyan kia tun ma saasi eniyen oooo kia ma da ifa
afuye gege fun ayan, kiatun mawa se arinako fun adire ewu
nla ni oooo.
HUMMM IBA OLOHUN LOKE OBA OGA AGBA IBA EYIN
Jagun trado medical care
08103544510 whatsapp

Address

Ogere
234

Opening Hours

Monday 09:00 - 18:35
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00
Sunday 09:00 - 17:00

Telephone

08103544510

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when JAGUN Trado Medical CARE posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to JAGUN Trado Medical CARE:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram