Omogiesi Tv

Omogiesi Tv Omogiesi TV jẹ ikanni ti a ti n se agbeyẹwo awon nkan ajogunba awon baba wa.

02/11/2023

Very good and knowlegdeable pable

https://youtu.be/rebSyG_oH9s
09/12/2022

https://youtu.be/rebSyG_oH9s

Asiri yi je asiri ti a ti danwo daada to si sise gege bi a se royin re, iwo ti o ba wa lo asiri yi ti o o ri to iye owo ti o ye ki o ri, dakun gbiyanju ki o ...

https://youtu.be/BkyfeErOmtU
06/12/2022

https://youtu.be/BkyfeErOmtU

Aseje yi wa fun obinrin ti n wa oyun, yala eniti o ni idaduro tabi ko ti e tii ni oyun ri rara, e je ki a gbiyanju re wo, o dara pupo

https://youtu.be/-RNRp1eCkhQ
04/12/2022

https://youtu.be/-RNRp1eCkhQ

OSE YI JE OSE TI ENIYAN MA N LO NIGBA TI KO BA SI OJUTU NINU IRIN AJO EDA MO, TI GBOGBO ONA TI DI, ASEGUN YI MA N GBEMI OTA TO BAN DI WA LOWO NI O, SUGBON MO...

https://youtu.be/HUn8gEwfLpU
01/12/2022

https://youtu.be/HUn8gEwfLpU

EYONU OSOLE YI YARA MU OWO WOLE PAAPA JULO NI ASIKO TI A BA NILO INAWO PAJAWIRI, SUGBON E JE KI A NI ISE KAN PATO TI N MU OWO WA O

https://youtu.be/oDnfjd2xSsY
29/11/2022

https://youtu.be/oDnfjd2xSsY

Obinrin ma n lo ileke yi lati fi ife si okan oko re, nitoripe oro ife laarin oko ati iyawo ni agbara pupo, ti obinrin ba kọ lati se amojuto awon nkan to yẹ k...

29/11/2022

HMM! OPOLOPO OBINRIN NI KO MO WIPE GBOGBO OHUN TI N DAN KO NI WURA

Omogiesi TV jẹ ikanni ti a ti n se agbeyẹwo awon nkan ajogunba awon baba wa.

29/11/2022

Address

Ita Olookan Street
Osogbo
230263

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Omogiesi Tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Omogiesi Tv:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram