22/10/2025
IFA OSHOLE ONITIKUTI 💯
ìṣe yiii je ifa nla kosi eniti kole lo ise yiii gbogbo ìṣe ti aba nse kosi eniti obalo ise ti koni sise fun mose kosise kosi nibe oo hmmmmm ogun toma sise ko need aro ye but ridaju wipe bí abati ni kose ni kose ooo toba ro eh lorun jeki awon toba mo nipa rẹ ba eh se oni idi ooo kosi ri daju wipe oni awon imule tabi ebe agba to nlo nile tori ise yii amarin ninu aye bigba ti eyan base oogun owo ni (Note ise yii kise ogun owo ooo nd kosini atunbotan kankan nínú o) sari daju wipe o mo nipa rẹ koto dawo le ise na
ISE TI ISE YII NSE LE YII 👇
omamu awon onibara ti won ni owo lọ́wọ́ wa fun eh
oma wu awon oloore nla wa fun en
osi masi ona ire nla fun eh
arisiki tosi madi ọjọ́ ale loma fun eh lenu ise re
Abi nibi oko oowo re abi nínú irin ajo ola re
osima ntun alamori eda to si ire yala eniti aje batitan lara rẹ
ISE NA LO BÁYÌÍ 👇
ori aja 🐕 tutu kan, odidi akan 🦀 tope kan,ewe ọ̀gẹ̀dẹ̀ agbagba topo die,ewe itipon ola tutu,ewe sefunsefun,ewe onitikuti tutu,ewe sapo tutu,odidi atare nla kan,koro efun mewa,koro osun ọgbọ́n,ao jo won papo aolo kuna aote ni ifa osa meji aope gbólóhùn rẹ si aoro sinu ado ide nla tàbí karo sinu sere nla kan (note ori ajá yen lama kọ́kọ́ fi tẹ́lẹ̀ inu àpe o kato ko awon eroja yoku le lori) ao mafi oti tobani agbara lo laaro pelu pipe gbólóhùn re nasi
GBÓLÓHÙN RẸ 👇
Esalesa 3× Akandudu 3× Akangirigiri 3× Ajagunna 3× Awon ni baba alawo tose ifa fun Orunmila, ni joti Orunmila n sunkún ifa ọlá Oojo won ni Orunmila bawo ni ose jẹ? Orunmila ni eyin komope ni lanla ni sapo nru we ninu igbó ewu nlanla ni ọ̀gẹ̀dẹ̀ agbagba n wo Orunmila ni odi jagidi, Orunmila ni odi jagada, Emi LML tigbe ori aja wasile aye ,Orisa Oke Toda Aja loni Aja kogbodo fi ori ru ẹrú Oni ki Aja kosi mani ile lori,wagba wagba la npe aja Osa meji sebi ìwọ ni oru igba Ola Aja wasile aye lọ́jọ́ sì, Osa meji walo ru ire Aje temi Wa fun mi loni Osun loni ki Ewa fi ire aje temi sun mibo,Efun loni ki ewa mafunmi ni owo temi loni iyoku labe comment.....