Alade Onimole

Alade Onimole Welcome to our page dedicated to Isese traditions!

Yoruùbá sọpé ;: kádúró kákásàn                             kábẹ̀rẹ̀ kákásàn                             Òrìṣà òkè ló mọ ...
06/10/2024

Yoruùbá sọpé ;: kádúró kákásàn
kábẹ̀rẹ̀ kákásàn
Òrìṣà òkè ló mọ ẹni tí yó fi dídùn
ọsàn lélọ́wọ́

Olódùmarè má jẹ́ kín n rí ìkorò ayé. Àmín Àṣẹ Èdùmàrè 🙏🙏🙏

*ÌṢẸ̀ṢE CALENDAR FOR THE MONTH OF AUGUST, 2023* 01. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn, Yemọja, Olókun, Ẹ̀là**O2. Ògún, Ìja,...
01/08/2023

*ÌṢẸ̀ṢE CALENDAR FOR THE MONTH OF AUGUST, 2023*

01. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn, Yemọja, Olókun, Ẹ̀là**
O2. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinlẹ̀.
03. Ṣàngó/Jàkúta, Ọya, Baáyànnì, Aganjú, Ọbalúayé/Ṣànpọ̀nná, Nàná-Bùkúù.
04. Ọbàtálá/Òrìṣà-Ńlá, Yemòó, Èṣù, Egúngún, Ẹgbẹ́-Ọ̀gbà/Alárá-Igbó, Orò, Ẹ̀lúkú, Agẹmọ, Òrìṣà Òkè, Ògìyán/Ògìrììyán.
O5. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn, Yemọja, Olókun, Ẹ̀là***
06. Ògún, ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinlẹ̀.
07. Șàngó/Jàkúta, Ọya, Baáyànnì, Aganjú, Ọbalúayé/Ṣànpọ̀nná, Nàná-Bùkúù.
08. Ọbàtálá/Òrìṣà-Ńlá, Yemòó, Èṣù, Egúngún, Ẹgbẹ́-Ọ̀gbà/Alárá-Igbó, Orò, Ẹ̀lúkú, Agẹmọ, Òrìṣà Òkè, Ògìyán/Ògìrììyán.
09. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn, Yemọja, Olókun, Ẹ̀là.
10. Ogún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinlẹ̀.
11. Șàngó/Jàkúta, Ọya, Baáyànnì, Aganjú, Ọbalúayé/Ṣànpọ̀nná, Nàná-Bùkúù.
12. Ọbàtálá/Òrìṣà-Ńlá, Yemòó, Èṣù, Egúngún, Ẹgbẹ́-Ọ̀gbà/Alárá-Igbó, Orò, Ẹ̀lúkú, Agẹmọ, Òrìṣà-Òkè, Ògìyán/Ògìrììyán.
13. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn, Yemọja, Olókun, Ẹ̀là****
14. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinlẹ̀.
15. Ṣàngó/Jàkúta, Ọya, Baáyànnì, Aganjú, Ọbalúayé/Ṣànpọ̀nná Nàná-Bùkúù.
16. Ọbàtálá/Òrìṣà-Ńlá, Yemòó, Èṣù, Egúngún, Ẹgbẹ́-Ọ̀gbà/Alárá-Igbó, Orò, Ẹ̀lúkú, Agẹmọ, Òrìṣà-Òkè, Ògìyán/Ògìrììyán.
17. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn, Yemọja, Olókun, Ẹ̀là**
18. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinlẹ̀.
19. Șàngó/Jàkúta, Ọya, Baáyànnì, Aganjú, Ọbalúayé/Ṣànpọ̀nná, Nàná-Bùkúù.
20. Ọbàtálá/Òrìṣà-Ńlá, Yemòó, Èṣù, Egúngún, Ẹgbẹ́-Ọ̀gbà/Alárá-Igbó, Orò, Ẹ̀lúkú, Agẹmọ, Òrìṣà-Òkè, Ògìyán/Ògìrììyán.
21. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn, Yemọja, Olókun, Ẹ̀là***
22. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinlẹ̀.
23. Ṣàngó/Jàkúta, Ọya, Baáyànnì, Aganjú, Ọbalúayé/Ṣànpọ̀nná, Nàná-Bùkúù.
24. Ọbàtálá/Òrìṣà-Ńlá, Yemòó, Èṣù, Egúngún, Ẹgbẹ́-Ọ̀gbà/Alárá-Igbó, Orò, Ẹ̀lúkú, Agẹmọ, Òrìṣà-Òkè, Ògìyán/Ògìrììyán.
25. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn,
Yemọja, Olókun, Ẹ̀là
26. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinlẹ̀.
27. Șàngó/Jàkúta, Ọya, Baáyànnì, Aganjú, Ọbalúayé/Ṣànpọ̀nná, Nàná-Bùkúù.
28. Ọbàtálá/Òrìṣà-Ńlá, Yemòó, Èṣù, Egúngún, Ẹgbẹ́-Ọ̀gbà/Alárá-Igbó, Orò, Ẹ̀lúkú, Agẹmọ, Òrìṣà Òkè, Ògìyán/Ògìrììyán.
29. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn, Yemọja, Olókun, Ẹ̀là****
30. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinẹ̀.
31. Șàngó/Jàkúta, Ọya, Baáyànnì, Aganjú, Ọbalúayé/Ṣànpọ̀nná, Nàná-Bùkúù.

*Note* :
**** Ìtàdógún - Ọ̀ṣẹ̀ Awo.
*** Isán - Ọ̀ṣẹ̀ Awo.
** Ọrún - Ọ̀ṣẹ̀ Awo.

Ọ̀rọ̀ àgbà kan sọ pé '' ọjọ́ a bágùn kọ́ni àákan ọ̀run '' OLÓDÙMARÈ má jẹ́ kí ire mi pẹ́ mọ́ tí yó fidé Àṣẹ ooooooo
25/07/2023

Ọ̀rọ̀ àgbà kan sọ pé '' ọjọ́ a bágùn kọ́ni àákan ọ̀run '' OLÓDÙMARÈ má jẹ́ kí ire mi pẹ́ mọ́ tí yó fidé Àṣẹ ooooooo

IFÁ lọba Òrìsà lọsìn Olódùmarè nìkan ni ọba àágbíyè le  Olódùmarè dákun má padà lẹ́yìn mi àti àwọn olólùfẹ́ mi
16/07/2023

IFÁ lọba Òrìsà lọsìn Olódùmarè nìkan ni ọba àágbíyè le

Olódùmarè dákun má padà lẹ́yìn mi àti àwọn olólùfẹ́ mi

THREE WAYS TO SOLVE MANKIND PROBLEM1. IFA consultation2. Sacrifice3. Believe in IFAAs a babalawo, God create us to help ...
12/07/2023

THREE WAYS TO SOLVE MANKIND PROBLEM
1. IFA consultation
2. Sacrifice
3. Believe in IFA
As a babalawo, God create us to help people to solve any kind of spiritual problem or physical problem in which affecting in human life.

Ifa Consultation and Sacrifice

Both work together, Ifa's consultation is called "Idafa" while the sacrifice is "Ebo" People consult Ifa when there is a problem or they just want to know about their life in general. After Ifa talked about the problem, he prescribes Ebo articles to the priest of Ifa (babalawo) who makes the consultation. The articles are used to make Ebo about the problem and thus solve it.

Esu is the messenger between heaven and earth,

Welcome to our page dedicated to Isese traditions!Isese is a traditional religion that originated in West Afric...
12/07/2023

Welcome to our page dedicated to Isese traditions!
Isese is a traditional religion that originated in West Africa and is still widely practiced in the region today. It is based on the belief in a supreme being, Orisa, and a system of divination through which practitioners seek guidance and insight.
Our page aims to provide a space for learning and sharing about Isese traditions, including its history, beliefs, practices, and rituals. We strive to create an inclusive and respectful community where people from all backgrounds can come together to explore and appreciate the richness and diversity of this ancient religion.
Whether you are a curious newcomer or an experienced practitioner, we hope you will find our page informative, engaging, and inspiring. We encourage you to ask questions, share your own experiences, and connect with others who share your interest in Isese traditions.
Thank you for joining us on this journey of discovery and learning. Ashe!

Address

Ile Ago Omiseyi Isaleoyo
Oyo

Telephone

+2348163801341

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Alade Onimole posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Alade Onimole:

Share