20/02/2024
Yoruba ni gbogbo Ile kile ni anfani lati gba oluko Ori ayelujara fun awon Omo wa tabi awa paapaa lati ko ede abinibi wa.
Yala nipa kiko ati kika ede yoruba ni, tabi sise idamo oruko owo currency ni ede abinibi Yoruba. Boya a si ni iwe eyi ti a fe yi pada si ede yoruba ti okun rere. Pe si ori ago ero ipe yii: 08103976873 tabi o fe ba wa soro lori Whatsapp 09071835964.