
07/12/2023
Iya Abiye ni mi 2+ ke mi ma se ke mi ma se iya abirorun iya abiye nimi A dupe fun olorun lori ile ise Lomona Naturalist hosp lati jan to dec fun abo iyanu ati aseyori asegbayi gbogbo eyin ololufe wa abiye le ma bi eni nwa oyun a ri oyun alalubarika gbogbo oloyun a o ni ba oyu ku lase edumare iwonba eyi toku ki odun yi pari a ni ba odun lo tomotomo tayataya tokotoko lase edumare oju gbogbo wa a ri amodun. Ase Ase Ase wa