
16/01/2024
ASEJE ATI OSE OSOLE TODAJU
((08143953689))
Ewe peregun tutu ti o po die,
Ewe emu tutu ti o po die,
Eran elede bansi kan,
Ewe sawerepepe tutu ti o po die,
Eyele funfun ooye kan,
Awo eeta.
Ike funfun olomori,
Ose dudu,
Oga ooye kan.
SISE RE:-a o pin awon nkan wonyi si meji, a o koko gun eran elede na ti yoo kunna dada, a o wa da awon nkan toku si, a o wa gun ti yoo kunna Dada, a o wa gun mo ose dudu, a o wa fi ori po, leyin eyi a o wa pa eyele na, a o wa ro eje eyele na sori ose na, a o wa po mo ose na, leyin eyi a o wa fi oga ooye tele inu ike funfun olomori, a o wa fa ose na le oga ooye na mole, a o wa gbe pamo fun ojo meje nibi ti idi re koti nikanle.
Lati owo ifabebi alado osha ewenje Traditional Herbalist
Wiwe re:-a o ma we ose na larolaro pelu kainkan ibile ati adura.
ASEJE RE:-a o lo idakeji awon nkan na ti yoo kunna dada, a o wa da sinu ikoko aseje, leyin eyi a o tu iye eyele ti a fi eje po ose na, a o wa ge eyele si ona merindinlogun (16), a o wa ko sinu ikoko aseje na, a o wa se l'epo-n'iyo, ti o ba jina tan, a o wa so sori osuka a*o funfun.
JIJE RE:-nigbati a ba fe je aseje na, a o ro a*o funfun, leyin eyi a o wa se adura owo nlanla si, a o wa je aseje na, leyin ti a ba je aseje na tan, a o ko awon egungun eyele na pada sinu ikoko aseje na, a o lo ri ikoko aseje na mole si ori akitan ti won ko le ma da ile si lojumo.
SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO
((08143953689))
RIDAJU WIPE O FI COMMENT RE SE ADURA TOBA WUN E FUN WA (COMMENT LIKE AND SHARE)
ENITI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE TABI TIKO MA BI O FESE KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ALE RAN YIN LOWO LATI BAYIN se ((08143953689))
FUN IBEERE ABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI OUN DOJUKO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((08143953689)) TIO BANI IGBAGBO
IKILO PATAKI:-
1:- MAPE MI FUN IBEERE TIKONI ITUMO..
2:-MAWA LATI TORO ASIRI LAINI OWO AJEGUN LOWO.